Kò ṣe é má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ọ́

Lori Koṣe Ma Gbọọ wa fun ti ọsẹ yii, ajọ to n kede bi oju ọjọ yoo ṣe ri ni Naijiria, NIMET, ti kilọ arọọda ojo lawọn ipinlẹ kan ni Naijiria.

Wọn ni omiyale, ara ati iji lile le maa pẹlu ojo to n rọ lai ṣiwọ.

Amọ ṣa, Nimet ti ṣalaye awọn ọna abayọ si ojo ti wọn ni yoo ṣi tun rọ ọhun.

Idaluu niṣelu, lo difa fun ilu kan ti wọn ki i fẹ obinrin pupa niyawo, afi dudu bii koro iṣin

Alaye nipa iroyin naa wa ninu oju opo yii.